Numeri 2:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-egbèje (53,400). Faic an caibideilYoruba Bible30 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbaaje ati irinwo (53,400). Faic an caibideilBibeli Mimọ30 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje. Faic an caibideil |