Numeri 2:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá-mẹ́tà-dínlógún ó-lé-egbèje (35,400). Faic an caibideilYoruba Bible23 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400). Faic an caibideilBibeli Mimọ23 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹtadilogun o le egbeje. Faic an caibideil |