Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 2:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-igba (32,200).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

21 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaafa ó lé igba (32,200).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

21 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilogun o le igba.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 2:21
4 Iomraidhean Croise  

Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Manase jẹ́ ẹgbàá ẹ́rìndínlógún ó-lé-igba (32,200).


Ẹ̀yà Manase ni yóò tẹ̀lé wọn. Olórí Manase ni Gamalieli ọmọ Pedasuri.


Ẹ̀yà Benjamini ni yóò tẹ̀lé e. Olórí Benjamini ni Abidani ọmọ Gideoni.


Wọ̀nyí ni ìdílé Manase tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin (52,700).


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan