Numeri 2:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta. (40,500). Faic an caibideilYoruba Bible19 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbẹta (40,500). Faic an caibideilBibeli Mimọ19 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ọkẹ meji o le ẹdẹgbẹta. Faic an caibideil |