Numeri 2:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mọ́kàn-dínlọ́gbọ̀n ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbéje. (59,300). Faic an caibideilYoruba Bible13 Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọ́n jẹ́ ẹgbaa mọkandinlọgbọn ó lé eedegbeje (59,300). Faic an caibideilBibeli Mimọ13 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mọkandilọgbòn o le ẹdegbeje. Faic an caibideil |