Numeri 19:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Àlùfáà yóò mú igi kedari, hísópù àti òwú òdòdó yóò sì jù wọ́n sí àárín ọ̀dọ́ abo màlúù tí a ń sun. Faic an caibideilYoruba Bible6 Kí alufaa ju igi kedari ati hisopu ati aṣọ pupa sinu iná náà. Faic an caibideilBibeli Mimọ6 Ki alufa na ki o mú igi opepe, ati hissopu, ati ododó, ki o si jù u sãrin ẹgbọrọ abomalu ti a nsun. Faic an caibideil |