Numeri 15:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Ẹ ṣe bẹ́ẹ̀ fún ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn, iyekíye tí ẹ̀yin ìbá à pèsè. Faic an caibideilYoruba Bible12 Ẹ óo mú àwọn nǹkan tí a kà sílẹ̀ wá pẹlu olukuluku ẹran tí ẹ bá fẹ́ fi rúbọ. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Gẹgẹ bi iye ti ẹnyin o pèse, bẹ̃ni ki ẹnyin ki o ṣe si olukuluku gẹgẹ bi iye wọn. Faic an caibideil |