Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 13:11 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Láti inú ẹ̀yà Manase, (ẹ̀yà Josẹfu), Gaddi ọmọ Susi;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

11 láti inú ẹ̀yà Josẹfu, tí í ṣe ẹ̀yà Manase, ó rán Gadi, ọmọ Susi;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

11 Ninu ẹ̀ya Josefu, eyinì ni, ninu ẹ̀ya Manasse, Gadi ọmọ Susi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 13:11
4 Iomraidhean Croise  

Ó súre fún wọn lọ́jọ́ náà pé, “Ní orúkọ yín ni Israẹli yóò máa súre yìí pé: ‘Kí Ọlọ́run ṣe ọ́ bí i ti Efraimu àti Manase.’ ” Ó sì gbé Efraimu gẹ́gẹ́ bí ẹ̀gbọ́n sí Manase.


Láti inú ẹ̀yà Sebuluni, Daddieli ọmọ Sodi;


Láti inú ẹ̀yà Dani, Ammieli ọmọ Gemalli;


Uma, Afeki àti Rehobu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan