Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 10:26 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

26 Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

26 Pagieli ọmọ Okirani ni olórí ẹ̀yà Aṣeri.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

26 Ati olori ogun ẹ̀ya awọn ọmọ Aṣeri ni Pagieli ọmọ Okrani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 10:26
4 Iomraidhean Croise  

Láti ọ̀dọ̀ Aṣeri, Pagieli ọmọ Okanri;


Lákòótan, àwọn ọmọ-ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dani lábẹ́ ọ̀págun wọn. Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai ni ọ̀gágun wọn.


Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali;


Pagieli ọmọ Okanri, olórí àwọn ọmọ Aṣeri ni ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kọkànlá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan