Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 10:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

19 Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Simeoni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

19 Ṣelumieli ọmọ Suriṣadai ni olórí ẹ̀yà Simeoni.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

19 Ati olori ogun ẹ̀ya awọn ọmọ Simeoni ni Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 10:19
4 Iomraidhean Croise  

Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai;


Àwọn ìpín ti ibùdó ti Reubeni ló gbéra tẹ̀lé wọn, lábẹ́ ọ̀págun wọn. Elisuri ọmọ Ṣedeuri ni ọ̀gágun wọn.


Eliasafu ọmọ Deueli ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Gadi.


Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai, olórí àwọn ọmọ Simeoni ni ó mú ọrẹ wá ní ọjọ́ karùn-ún.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan