Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 10:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Netaneli ọmọ Ṣuari ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Isakari;

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

15 Netaneli ọmọ Suari ni olórí ẹ̀yà Isakari.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

15 Olori ogun ẹ̀ya awọn ọmọ Issakari si ni Netaneli ọmọ Suari.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 10:15
4 Iomraidhean Croise  

Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Ṣuari;


Àwọn ìpín ti ibùdó Juda ló kọ́kọ́ gbéra tẹ̀lé wọn lábẹ́ ogun wọn Nahiṣoni ọmọ Amminadabu ni ọ̀gágun wọn.


Eliabu ọmọ Heloni ni ọ̀gágun ni ìpín ti ẹ̀yà Sebuluni.


Ní ọjọ́ kejì ni Netaneli ọmọ Ṣuari olórí àwọn ọmọ Isakari mú ọrẹ tirẹ̀ wá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan