48 Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé,
48 nítorí pé OLUWA ti sọ fún Mose pé,
48 Nitoripe OLUWA ti sọ fun Mose pe,
A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.
“Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli: