Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:43 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

43 Iye àwọn tí a kà nínú ẹ̀yà Naftali jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n ó-lé-egbèje (53,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

43 jẹ́ ẹgbaa mẹrindinlọgbọn ó lé egbeje (53,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

43 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Naftali, o jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:43
4 Iomraidhean Croise  

Láti ìran Naftali: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún ó lé, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.


Wọ̀nyí ni àwọn ènìyàn tí Mose àti Aaroni kà, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn olórí méjìlá (12) fún Israẹli, tí ẹnìkọ̀ọ̀kan ṣojú fún ìdílé rẹ̀.


Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-egbèje (53,400).


Wọ̀nyí ni ìdílé ti Naftali gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, àwọn tí a kà nínú wọn jẹ́ ẹgbàá-méjìlélógún ó-lé-egbèje (45,400).


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan