Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

29 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Isakari jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (54,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

29 jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400).

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

29 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Issakari, o jẹ́ ẹgbã mẹtadilọgbọ̀n o le irinwo.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:29
4 Iomraidhean Croise  

Láti ìran Isakari: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n le lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.


Láti ìran Sebuluni: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.


Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (54,400).


Wọ̀nyí ni ìdílé Isakari gẹ́gẹ́ bí àwọn tí a kà nínú wọn tí iye wọn sì jẹ́ ẹgbàá-méjìlélọ́gbọ̀n ó-lé-ọ̀ọ́dúnrún (64,300).


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan