Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Numeri 1:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Láti ọ̀dọ̀ Naftali, Ahira ọmọ Enani.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

15 Ahira ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà Nafutali.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

15 Ti Naftali; Ahira ọmọ Enani.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Numeri 1:15
5 Iomraidhean Croise  

Láti ọ̀dọ̀ Gadi, Eliasafu ọmọ Deueli;


Àwọn wọ̀nyí ni wọ́n yàn nínú àwùjọ ènìyàn, olórí àwọn ẹ̀yà baba wọn. Àwọn ni olórí àwọn ẹbí Israẹli.


Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali;


Ẹ̀yà Naftali ni yóò kàn lẹ́yìn wọn. Olórí Naftali ni Ahira ọmọ Enani.


Ahira ọmọ Enani, olórí àwọn Naftali ni ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kejìlá.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan