Marku 7:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin kò si jẹ́ kí ó ṣe ohunkóhun fún baba tàbí ìyá rẹ̀ mọ́. Faic an caibideilYoruba Bible12 ẹ ti gbà pé ẹni bẹ́ẹ̀ kò ní ohunkohun í ṣe fún baba tabi ìyá rẹ̀ mọ́. Faic an caibideilBibeli Mimọ12 Bẹ̃li ẹnyin ko si jẹ ki o ṣe ohunkohun fun baba tabi iya rẹ̀ mọ́; Faic an caibideil |