Marku 5:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Nígbà náà ni ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jesu gidigidi, kí ó má ṣe rán àwọn jáde kúrò ní agbègbè náà. Faic an caibideilYoruba Bible10 Ó bá bẹ̀rẹ̀ sí bẹ Jesu títí pé kí ó má ṣe lé wọn jáde kúrò ní agbègbè ibẹ̀. Faic an caibideilBibeli Mimọ10 O si bẹ̀ ẹ gidigidi pe, ki o máṣe rán wọn jade kuro ni ilẹ na. Faic an caibideil |