Marku 5:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Wọ́n lọ sí apá kejì adágún ní ẹ̀bá ilẹ̀ àwọn ará Gadara. Faic an caibideilYoruba Bible1 Jesu lọ sí òdìkejì òkun ní ilẹ̀ àwọn ará Geraseni. Faic an caibideilBibeli Mimọ1 NWỌN si wá si apa keji okun ni ilẹ awọn ara Gadara. Faic an caibideil |