Marku 13:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Kí ẹni tí ó wà lóko má ṣe padà sẹ́yìn láti wá mú aṣọ rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible16 Kí alágbàro ní oko má ṣe dúró mú ẹ̀wù rẹ̀ tí ó bọ́ sílẹ̀. Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Ati ki ẹniti mbẹ li oko ki o maṣe pada sẹhin wá lati mu aṣọ rẹ̀. Faic an caibideil |