Marku 11:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Àti àwọn tí ń lọ níwájú, àti àwọn tí ń bọ̀ lẹ́yìn, gbogbo wọn sì ń kígbe wí pé, “Hosana!” “Olùbùkún ni ẹni náà tí ó ń bọ̀ wà ní orúkọ Olúwa!” Faic an caibideilYoruba Bible9 Àwọn tí ó ń lọ ní iwájú ati àwọn tí ó ń bọ̀ ní ẹ̀yìn ń kígbe pé, “Hosana! Olùbùkún ni ẹni tí ń bọ̀ ní orúkọ Oluwa. Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Ati awọn ti nlọ niwaju, ati awọn ti mbọ̀ lẹhin, nkigbe wipe, Hosanna; Olubukun li ẹniti o mbọ̀wá li orukọ Oluwa: Faic an caibideil |