Marku 10:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Nítorí náà ohun ti Ọlọ́run bá sọ dọ̀kan, ki ẹnikẹ́ni máa ṣe yà wọ́n.” Faic an caibideilYoruba Bible9 Nítorí náà ohun tí Ọlọrun bá ti so pọ̀, kí ẹnikẹ́ni má ṣe yà á.” Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Nitorina ohun ti Ọlọrun ba so ṣọkan, ki enia ki o máṣe yà wọn. Faic an caibideil |