Marku 10:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Òun àti ìyàwó rẹ̀ yóò di ara kan náà. Nítorí náà, wọn kì í túnṣe méjì mọ́ bí kò ṣe ẹyọ ọ̀kan ṣoṣo. Faic an caibideilYoruba Bible8 àwọn mejeeji yóo wá di ọ̀kan. Wọn kì í tún ṣe ẹni meji mọ́ bíkòṣe ọ̀kan. Faic an caibideilBibeli Mimọ8 Awọn mejeji a si di ara kan: nitorina nwọn kì iṣe meji mọ́, bikoṣe ara kan. Faic an caibideil |