Marku 10:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní7 Nítorí ìdí èyí, ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀ yóò sì fi ara mọ́ aya rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible7 Nítorí èyí ni ọkunrin yóo ṣe fi baba ati ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóo wá fi ara mọ́ iyawo rẹ̀; Faic an caibideilBibeli Mimọ7 Nitori eyi li ọkunrin yio ṣe fi baba ati iya rẹ̀ silẹ ti yio si faramọ aya rẹ̀; Faic an caibideil |