Luku 24:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Ṣùgbọ́n a rú wọn lójú, kí wọn má le mọ̀ ọ́n. Faic an caibideilYoruba Bible16 Ṣugbọn ó dàbí ẹni pé a dì wọ́n lójú, wọn kò mọ̀ pé òun ni. Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Ṣugbọn a rú wọn li oju ki nwọn ki o máṣe le mọ̀ ọ. Faic an caibideil |