Luku 22:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Wọ́n sì wí fún un pé, “Níbo ni ìwọ ń fẹ́ kí á pèsè sílẹ̀?” Faic an caibideilYoruba Bible9 Wọ́n bi í pé, “Níbo ni o fẹ́ kí á lọ ṣe ètò sí?” Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Nwọn si wi fun u pe, Nibo ni iwọ nfẹ ki a pèse sile? Faic an caibideil |