Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Luku 18:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Olúwa sì wí pé, “Ẹ gbọ́ bí aláìṣòótọ́ onídàájọ́ ti wí!

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

6 Oluwa wá sọ pé, “Ẹ kò gbọ́ ohun tí adájọ́ alaiṣootọ yìí wí!

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

6 Oluwa si wipe, Ẹ gbọ́ bi alaiṣõtọ onidajọ ti wi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Luku 18:6
4 Iomraidhean Croise  

Kí ẹ̀yin lè jẹ́ ọmọ Baba yín ti ń bẹ ní ọ̀run. Ó mú kí oòrùn rẹ̀ ràn sára ènìyàn búburú àti ènìyàn rere, ó rọ̀jò fún àwọn olódodo àti fún àwọn aláìṣòdodo.


Nígbà tí Olúwa sì rí i, àánú rẹ̀ ṣe é, ó sì wí fún un pé, “Má sọkún mọ́.”


Nígbà tí Johanu sì pe àwọn méjì nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó rán wọn sọ́dọ̀ Olúwa, wí pé, “ìwọ ni ẹni tí ń bọ̀, tàbí kí a máa retí ẹlòmíràn?”


ẹyin kò ha ń dá ara yín sí méjì nínú ara yín, ẹ̀yin kò sì di onídàájọ́ tí ó ní èrò búburú bí?


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan