Luku 11:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Àwọn ẹlòmíràn sì ń dán an wò, wọ́n ń fẹ́ ààmì lọ́dọ̀ rẹ̀ láti ọ̀run wá. Faic an caibideilYoruba Bible16 Àwọn ẹlòmíràn ń dẹ ẹ́, wọ́n ń bèèrè àmì ọ̀run láti ọ̀dọ̀ rẹ̀. Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Awọn ẹlomiran si ndan a wò, nwọn fẹ àmi lọdọ rẹ̀ lati ọrun wá. Faic an caibideil |