Luku 1:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Ó sì ṣe, nígbà tí ọjọ́ iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ pé, ó lọ sí ilé rẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible23 Nígbà tí ó parí àkókò tí yóo fi ṣiṣẹ́ alufaa ninu Tẹmpili, ó pada lọ sí ilé rẹ̀. Faic an caibideilBibeli Mimọ23 O si ṣe, nigbati ọjọ iṣẹ isin rẹ̀ pe, o lọ si ile rẹ̀. Faic an caibideil |