Luku 1:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Àwọn ènìyàn sì ń dúró de Sekariah, ẹnu sì yà wọ́n nítorí tí ó pẹ́ nínú tẹmpili. Faic an caibideilYoruba Bible21 Àwọn eniyan ti ń retí Sakaraya. Ẹnu yà wọ́n pé ó pẹ́ ninu iyàrá Tẹmpili. Faic an caibideilBibeli Mimọ21 Awọn enia si duro dè Sakariah, ẹnu si yà wọn nitoriti o pẹ ninu tẹmpili. Faic an caibideil |