Joṣua 4:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 “Pàṣẹ fún àwọn àlùfáà tí o ń ru àpótí ẹ̀rí, kí wọn kí ó jáde kúrò nínú odò Jordani.” Faic an caibideilYoruba Bible16 “Pàṣẹ fún àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Ẹ̀rí pé kí wọ́n jáde kúrò ninu odò Jọdani.” Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Paṣẹ fun awọn alufa ti o rù apoti ẹri nì pe, ki nwọn ki o ti inu Jordani jade. Faic an caibideil |