Joṣua 18:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 ṣùgbọ́n ó ku ẹ̀yà méje nínú àwọn ọmọ Israẹli tí kò tí ì gba ogún ìní wọn. Faic an caibideilYoruba Bible2 Ó ku ẹ̀yà meje, ninu àwọn ẹ̀yà Israẹli, tí wọn kò tíì pín ilẹ̀ fún. Faic an caibideilBibeli Mimọ2 Ẹ̀ya meje si kù ninu awọn ọmọ Israeli, ti kò ti igbà ilẹ-iní wọn. Faic an caibideil |