Joṣua 17:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 (Manase lo ni ilẹ̀ Tapua, ṣùgbọ́n Tapua fúnrarẹ̀ to wà ni ààlà ilẹ̀ Manase jẹ ti àwọn ará Efraimu.) Faic an caibideilYoruba Bible8 Àwọn ọmọ Manase ni wọ́n ni ilẹ̀ Tapua, ṣugbọn ìlú Tapua gan-an, tí ó wà ní ààlà ilẹ̀ àwọn ọmọ Manase, jẹ́ ti àwọn ọmọ Efuraimu. Faic an caibideilBibeli Mimọ8 Manasse li o ní ilẹ Tappua: ṣugbọn Tappua li àla Manasse jẹ́ ti awọn ọmọ Efraimu. Faic an caibideil |