Joṣua 16:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 Èyí ni ilẹ̀ Efraimu, ní agbo ilé agbo ilé: Ààlà ìní wọn lọ láti Atarotu-Addari ní ìlà-oòrùn lọ sí Òkè Beti-Horoni. Faic an caibideilYoruba Bible5 Èyí ni ilẹ̀ tí àwọn ọmọ Efuraimu gbà, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn. Ààlà ilẹ̀ wọn ní apá ìlà oòrùn bẹ̀rẹ̀ láti Atarotu Adari, títí dé apá òkè Beti Horoni. Faic an caibideilBibeli Mimọ5 Àla awọn ọmọ Efraimu gẹgẹ bi idile wọn li eyi: ani àla ilẹ-iní wọn ni ìha ìla-õrùn ni Atarotu-adari, dé Beti-horoni òke; Faic an caibideil |