Joṣua 10:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti wọ́de ogun ní gbogbo òru náà láti Gilgali, Joṣua sì yọ sí wọn lójijì. Faic an caibideilYoruba Bible9 Joṣua jálù wọ́n lójijì, lẹ́yìn tí ó ti fi gbogbo òru rìn láti Giligali. Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Joṣua si yọ si wọn lojijì; o si gòke lati Gilgali lọ ni gbogbo oru na. Faic an caibideil |