Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Joṣua 1:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Báyìí ni Joṣua pàṣẹ fún olórí àwọn ènìyàn rẹ̀

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

10 Lẹ́yìn náà, Joṣua pàṣẹ fún gbogbo àwọn olórí àwọn eniyan náà, ó ní,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

10 Nigbana ni Joṣua paṣẹ fun awọn olori awọn enia wipe,

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Joṣua 1:10
3 Iomraidhean Croise  

“Ẹ la ibùdó já, kí ẹ sì sọ fún àwọn ènìyàn, ‘Ẹ pèsè oúnjẹ yín sílẹ̀. Ní ìwòyí ọ̀túnla, ẹ̀yin yóò la Jordani yìí kọjá, láti gba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún un yín láti ní.’ ”


Èmi kò ha ti pàṣẹ fún ọ bí? Jẹ́ alágbára kí o sì mú àyà le. Má ṣe bẹ̀rù, má sì ṣe rẹ̀wẹ̀sì, nítorí pé Olúwa à rẹ yóò wà pẹ̀lú rẹ ní ibikíbi tí ìwọ bá ń lọ.”


Lẹ́yìn ọjọ́ kẹta àwọn olórí la àárín ibùdó já.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan