Johanu 9:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Nítorí èyí ni àwọn òbí rẹ̀ fi wí pé, “Ẹni tí ó dàgbà ni òun, ẹ bi í léèrè.” Faic an caibideilYoruba Bible23 Nítorí èyí ni àwọn òbí ọkunrin náà ṣe sọ pé, “Kì í ṣe ọmọde, ẹ bi òun alára léèrè.” Faic an caibideilBibeli Mimọ23 Nitori eyi li awọn obi rẹ̀ fi wipe, Ẹniti o gbọ́njú ni iṣe; ẹ bi i lẽre. Faic an caibideil |