Johanu 8:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Nítorí náà àwọn Farisi wí fún un pé, “Ìwọ ń jẹ́rìí ara rẹ; ẹ̀rí rẹ kì í ṣe òtítọ́.” Faic an caibideilYoruba Bible13 Àwọn Farisi sọ fún un pé, “Ò ń jẹ́rìí ara rẹ, ẹ̀rí rẹ kò jámọ́ nǹkankan.” Faic an caibideilBibeli Mimọ13 Nitorina awọn Farisi wi fun u pe, Iwọ njẹri ara rẹ; ẹrí rẹ kì iṣe otitọ. Faic an caibideil |