Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 8:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Jesu sì lọ sí orí òkè olifi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

1 Ni olukuluku wọn bá lọ sí ilé wọn; ṣugbọn Jesu lọ sí Òkè Olifi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

1 JESU si lọ si ori òke Olifi.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 8:1
5 Iomraidhean Croise  

Bí wọ́n ti súnmọ́ Jerusalẹmu, tí wọ́n dé itòsí ìlú Betfage ní orí òkè Olifi, Jesu sì rán àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì,


Bí wọ́n ti súnmọ́ Betfage àti Betani ní ẹ̀yìn odi ìlú Jerusalẹmu, wọ́n dé orí òkè olifi. Jesu rán méjì nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ síwájú.


Bí Jesu si ti jókòó lórí òkè olifi tí ó kọjú sí tẹmpili, Peteru, Jakọbu, Johanu àti Anderu wà pẹ̀lú rẹ̀ níbẹ̀, wọ́n bi í léèrè ni ìkọ̀kọ̀ pé,


Bí ó sì ti súnmọ́ etí ibẹ̀ ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè olifi, gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn bẹ̀rẹ̀ sí í yọ̀, wọ́n sì fi ohùn rara yin Ọlọ́run, nítorí iṣẹ́ ńlá gbogbo tí wọ́n ti rí;


Wọ́n sì lọ olúkúlùkù sí ilé rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan