Johanu 7:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Nígbà tí ó ti sọ nǹkan wọ̀nyí fún wọn tan, ó dúró ní Galili síbẹ̀. Faic an caibideilYoruba Bible9 Nígbà tí ó wí báyìí tán, ó tún dúró ní ilẹ̀ Galili. Faic an caibideilBibeli Mimọ9 Nigbati o ti sọ nkan wọnyi fun wọn tan, o duro ni Galili sibẹ̀. Faic an caibideil |