Johanu 7:46 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní46 Àwọn ẹ̀ṣọ́ dáhùn wí pé, “Kò sí ẹni tí ó tí ì sọ̀rọ̀ bí ọkùnrin yìí rí!” Faic an caibideilYoruba Bible46 Àwọn ẹ̀ṣọ́ ọ̀hún bá dáhùn pé, “Ẹnikẹ́ni kò sọ̀rọ̀ bí ọkunrin yìí rí!” Faic an caibideilBibeli Mimọ46 Awọn onṣẹ dahùn wipe, Kò si ẹniti o ti isọ̀rọ bi ọkunrin yi ri. Faic an caibideil |