Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 6:34 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

34 Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Olúwa, máa fún wa ní oúnjẹ yìí títí láé.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

34 Wọ́n bá sọ fún un pé, “Alàgbà, máa fún wa ní oúnjẹ yìí nígbà gbogbo.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

34 Nigbana ni nwọn wi fun u pe, Oluwa, mã fun wa li onjẹ yi titi lai.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 6:34
4 Iomraidhean Croise  

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló ń béèrè pé, “Ta ni yóò ṣe rere fún wa?” Olúwa, Jẹ́ kí ojú rẹ mọ́lẹ̀ sí wa lára,


Obìnrin náà sì wí fún u pé, “Alàgbà, fún mi ní omi yìí, kí òǹgbẹ kí ó má ṣe gbẹ mí, kí èmi kí ó má sì wá fa omi níbí mọ́.”


Jesu dá wọn lóhùn ó sì wí pé, “Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún yín. Ẹ̀yin ń wá mi, kì í ṣe nítorí tí ẹ̀yin rí iṣẹ́ ààmì, ṣùgbọ́n nítorí ẹ̀yin jẹ àjẹyó ìṣù àkàrà.


Ọlọ́run àti Baba Olúwa wá Jesu Kristi, ẹni tí ó jẹ́ olùbùkún jùlọ láéláé mọ̀ pé èmi kò ṣèké.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan