Johanu 6:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Nígbà tí alẹ́ sì lẹ́, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí Òkun. Faic an caibideilYoruba Bible16 Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí èbúté, Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Nigbati alẹ si lẹ, awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ lọ sinu okun. Faic an caibideil |