Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 5:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Jesu wí fún un pé, “Dìde, gbé àkéte rẹ, kí o sì máa rìn.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

8 Jesu wí fún un pé, “Dìde, ká ẹní rẹ, kí o máa rìn.”

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

8 Jesu wi fun u pe, Dide, gbé akete rẹ, ki o si mã rin.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 5:8
5 Iomraidhean Croise  

Nígbà náà ni àwọn arọ yóò máa fò bí àgbọ̀nrín, àti ahọ́n odi yóò ké fún ayọ̀. Odò yóò tú jáde nínú aginjù àti àwọn odò nínú aṣálẹ̀.


Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ pé Ọmọ Ènìyàn ní agbára ní ayé láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì ni.” Ó sì wí fún arọ náà pé, “Dìde, sì gbé àkéte rẹ, kí o sì máa lọ ilé rẹ.”


“Mo wí fún ọ, dìde, gbé àkéte rẹ kí ó sì máa lọ ilé rẹ.”


Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin lè mọ̀ pé ọmọ ènìyàn ní agbára ní ayé láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji ni.” Ó wí fún ẹlẹ́gbà náà pé, “Mo wí fún ọ, dìde, sì gbé àkéte rẹ, kí o sì máa lọ sí ilé!”


Peteru sì wí fún un pé, “Aenea, Jesu Kristi mú ọ láradá; dìde kí ó sì tún àkéte rẹ ṣe.” Ó sì dìde lójúkan náà.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan