Johanu 5:31 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní31 “Bí èmi bá ń jẹ́rìí ara mi, ẹ̀rí mi kì í ṣe òtítọ́. Faic an caibideilYoruba Bible31 “Bí ó bá jẹ́ pé èmi ni mò ń jẹ́rìí ara mi, ẹ̀rí mi lè má jẹ́ òtítọ́. Faic an caibideilBibeli Mimọ31 Bi emi ba njẹri ara mi, ẹrí mi kì iṣe otitọ. Faic an caibideil |