Johanu 3:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Ọkùnrin kan sì wà nínú àwọn Farisi, tí a ń pè ní Nikodemu, ìjòyè kan láàrín àwọn Júù: Faic an caibideilYoruba Bible1 Ọkunrin kan wà ninu àwọn Farisi tí ń jẹ́ Nikodemu. Ó jẹ́ ọ̀kan ninu ìgbìmọ̀ àwọn Juu. Faic an caibideilBibeli Mimọ1 ỌKUNRIN kan si wà ninu awọn Farisi, ti a npè ni Nikodemu, ijoye kan ninu awọn Ju: Faic an caibideil |