Johanu 21:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nígbà tí Peteru rí i, ó wí fún Jesu pé, “Olúwa, Eléyìí ha ńkọ́?” Faic an caibideilYoruba Bible21 Nígbà tí Peteru rí i, ó bi Jesu pé, “Oluwa, eléyìí ńkọ́?” Faic an caibideilBibeli Mimọ21 Nigbati Peteru ri i, o wi fun Jesu pe, Oluwa, Eleyi ha nkọ́? Faic an caibideil |