Johanu 20:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 Nígbà náà ni Peteru àti ọmọ-ẹ̀yìn mìíràn náà jáde, wọ́n sì wá sí ibojì. Faic an caibideilYoruba Bible3 Peteru ati ọmọ-ẹ̀yìn náà bá jáde, wọ́n lọ sí ibojì náà. Faic an caibideilBibeli Mimọ3 Nigbana ni Peteru jade, ati ọmọ-ẹhin miran na, nwọn si wá si ibojì. Faic an caibideil |