Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




Johanu 20:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn náà sì tún padà lọ sí ilé wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

10 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn bá tún pada lọ sí ilé wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bibeli Mimọ

10 Bẹli awọn ọmọ-ẹhin na si tun pada lọ si ile wọn.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




Johanu 20:10
4 Iomraidhean Croise  

Nígbà náà ni Peteru dìde, ó súré lọ sí ibojì; nígbà tí ó sì bẹ̀rẹ̀, ó rí aṣọ àlà lọ́tọ̀ fúnrawọn, ó sì padà lọ sí ilé rẹ̀, ẹnu yà á sí ohun tí ó ṣe.


Kíyèsi i, wákàtí ń bọ̀, àní ó dé tan nísinsin yìí, tí a ó fọ́n yín ká kiri, olúkúlùkù sí ilé rẹ̀; ẹ ó sì fi èmi nìkan sílẹ̀: ṣùgbọ́n kì yóò sì ṣe èmi nìkan, nítorí tí Baba ń bẹ pẹ̀lú mi.


Ṣùgbọ́n Maria dúró létí ibojì lóde, ó ń sọkún: bí ó ti ń sọkún, bẹ́ẹ̀ ni ó bẹ̀rẹ̀, ó sì wo inú ibojì.


Wọ́n sì lọ olúkúlùkù sí ilé rẹ̀.


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan