Johanu 19:22 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 Pilatu dáhùn pé, ohun tí mo ti kọ, mo ti kọ ọ́. Faic an caibideilYoruba Bible22 Ṣugbọn Pilatu dá wọn lóhùn pé, “Ohun tí mo ti kọ, mo ti kọ ọ́ ná.” Faic an caibideilBibeli Mimọ22 Pilatu dahùn pe, Ohun ti mo ti kọ tan, mo ti kọ na. Faic an caibideil |
“Lọ, kí o kó gbogbo àwọn Júù tí ó wà ní Susa jọ, kí ẹ sì gbààwẹ̀ fún mi. Ẹ má ṣe jẹun tàbí omi fún ọjọ́ mẹ́ta, ní òru àti ní ọ̀sán. Èmi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi náà yóò gbààwẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin náà ti ṣe. Nígbà tí ẹ bá ṣe èyí, èmi yóò tọ ọba lọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó lòdì sí òfin. Bí mo bá sì ṣègbé, mo ṣègbé.”