Johanu 19:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní16 Nítorí náà ni Pilatu fà á lé wọn lọ́wọ́ láti kàn án mọ́ àgbélébùú. Àwọn ológun gba Jesu lọ́wọ́ Pilatu. Faic an caibideilYoruba Bible16 Pilatu bá fa Jesu fún wọn láti kàn mọ́ agbelebu. Wọ́n bá gba Jesu lọ́wọ́ Pilatu. Faic an caibideilBibeli Mimọ16 Awa kò li ọba bikoṣe Kesari. Nigbana li o fà a le wọn lọwọ lati kàn a mọ agbelebu. Wọ́n bá gba Jesu lọ́wọ́ Pilatu. Faic an caibideil |